Ijamba oko kan to sele ni opopona Ibadan si Oyo ni oti ran akeko Quantity Surveying kan ti ile eko giga Ibadan Poly Mefa lo si orun apapandodo ni osan yi...Ijamba oko na sele ni okan lara awon Tyre oko na be ti o si mu oko na gbe okiti....Gbogbo awon akeko ti won ku ni won ti gbe lo si ile igboku si ni ile iwosan Adeoyo, ti won si ko awon ti won fi ara pa lo si ile iwosan St.Patrick private hospital...Olorun ama ko wa yo ninu ewu o.
6 students of the Department of Quantity
Surveying, Ibadan Polytechnic, Oyo state, were confirmed dead while 13
others sustained various degrees of injuries in an auto crash which
occurred at Motunde, along Ibadan-Oyo Road on Monday, February 8. The
injured were taken to St. Patrick Private Hospital and General
Hospital,Oyo State while the remains of the dead were deposited at the
mortuary of Adeoyo State Hospital, Yemetu.
The accident reportedly occurred when the
vehicle somersaulted several times and hit the road divider as a result
of burst tyre. Sector Commander of the Federal Road Safety Commission
in Oyo State, Mr. Yusuf Salami, who confirmed the incident said details
were still being compiled.
Comments
Post a Comment