Pastor Adeboye lo se abewo si Ooni ti Ife osi gba adura fun.







Ooni ti Ife gba alejo Ojise Olorun Pastor Adeboye ni Aafin re ni oni...Inu awon mejeji dun lati ri ara won.Adeboye fi bi inu re didun ati ayo gba adura fun Ooni ti o si ku igbiyanju lati jeki ifowosowopo wa laarin gbogbo eya Yoruba.



Pastor Enoch Adeboye paid a second historic visit to the palace of the Ooni of Ife this morning Thursday February 11,2016... Pastor Adeboye is extremely happy about the positive move the current Ooni is taking decided to visit and pray for him again in his palace.he also encouraged him to forge ahead on the good course he had started

Comments