Posts

Arakunrin Bayo Omoboriowo ati Iyawo re ti bi Ibeji.

Awon agbenipa kan be ori odomode kunrin kan ni ipinle Rivers.

Saraki lo ki awon ti ogun bokoharam le ni Kuchigoro Abuja.

Julius Agwu ati iyawo re Ibere se ayeye odun kesan igbeyawo won.

Asoju Aare, Yemi Osijbanjo ti yan Dangote, Peterside ati Fashola sinu egbe Nigeria Industrial Policy and Competitiveness Advisory Council.

Ayeye igbeyawo omoba Adedapo Tejuoso.

Donald Duke ti pinu lati gbe igba fun ipo Aare.

Owo awon agbofinro ti ba awon adigunjale kan ni ipinle Benue.

Iyawo Aare, arabirin Aisha Buhari ti lo si ilu UK lati lo duro ti oko re.

Oni ni ojo ibi oserebirin Susan Peters.

Nnamdi Kanu se iranti awon akoni ati ajijagbara fun orilede Biafra to ti ku loju ogun.

Awon agbebon kan ti yin ibon pa Rasaq Bello oga agba NURTW ni Oshodi.

Awon agbebon kan pa omo ojise olorun kan ni ipinle Edo.

Tiger Woods ti da akeregbe bo ori. (OMUTI)

Awon eyan meji ti ku ninu ile alaja meta (3 storey building) to wo ni ipinle Eko.

Aworan Yemi Osinbajo,Asiwaju Bola Tinubu,Oba Rilwan Akiolu I nibi ayeye ojobi ipinle Eko.