Posts

Gbajugbaja odomode olorin Techno Miles ti ra oko ayokele tuntun.

Arun Monkey Pox ti de ilu Gboko ni ipinle Benue. +18

Arabirin kan ti ko lati ni ade ori nitori pe ko fe kuro ni Lekki. lol O ga o.

Awon to'ko ti'yawo meji kan bi ibeta leyin odun mokonkanla (11yrs) ti won tin wa omo ni ipinle Rivers.

O ma se o, Akeko ile iwe giga Auchi Polytechnic kan ku ninu ijamba oko leyin ojokan to keko jade.

Oga agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Tinubu lo'ni lo se abewo si Aare Buhari ni Aso Rock.

Awon aworan ipalemo fun igbeyawo gbajugbaja odomode olorin Oritsefemi ati iyawo afesona re Nabila.

Awon omo ologun Nigeria pa ikan ninu awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam ni ipinle Borno.

Arabirin omo odun mejidinlogoji to bi iberin ni ipinle Katsina ti ku.

O ma se o! Baba gbajugbaja oserebirin Mercy Aigbe ti ku.

Awon aworan nibi ayeye ikomo omobirin Gomina Abiola Ajimobi.

Otunba Gani Adams ti setan lati je oye Aare Ona Kakanfo elekarundinlogun ti ile Yoruba.

Awon odomodebirin meji kan ti sonu ni ipinle Bayelsa.

Oserebirin Ifunanya Igwe ti bi omobirin tuntun jojolo kan.

Odomode kunrin alawada Ebiye Victor ti setan lati gbe orebirin re Agnes Ejeme ni iyawo.

Awon eso Aare Buhari ko lati je ki Saraki ati Dogara ri Aare loni, ni ibudo Aare.

Hmmm, Ogbeni Freeze ti fi esun kan Timi Dakolo o, o so wipe arakunrin na n'je ise omoge kan nita.

Aworan Yemi Osinbajo,Ike Ekweremadu ati Yakubu Dogara nibi ipade adura fun orilede to waye ni aro kutu-kutu oni.

O ma se o! Baba arugbo kan daku, o si gba ibe ku ni iwaju ile ejo kotemilorun (magistrate court) ni ipinle Eko.

Awon agbofinro ti mu awon adigunjale meje, won si gba oko merindinlogbon lowo won ni ipinle Ogun.

Won ti fi oserebirin Tonto Dikeh je oye 'Adadioranma of Nollywood'. lo'ni.

Eto isinku awon ogofa eniyan (120people) ti awon daran-daran (herdsmen) pa ni ilu Zamfara.