Omi ayo meta si odo (3-0) ni egbe agbaboolu Arsenal na egbe agbaboolu Bate






Idije ifesewonse to waye laarin egbe agbaboolu Arsenal ati awon akegbe won lati egbe agbaboolu Bate lo pari si omi ayo meta si odo (3-0) nigbati egbe agbaboolu Arsenal gbe igba oroke.

Agbaboolu Zahkar Volkov lo koko gba omi ayo kan wole fun Arsenal, ti Shkordran Mustafi si gba omi ayo keji wole, ki Sokratis Papastathopoulos si fi oba le.

Aseyori yi lo ti sun egbe agbaboolu Arsenal soke si ninu idije UEFA Europa Leauge.

Comments