Awon Boko Haram un pa awon eyan Marun ni Cameroun

Awon obirin meji ni won blow arawon niDabanga ni Cameroun ti won si pa eyan marun, opolopo awon omo ologun Nigeria ti won ran lor lati ma moju to nkan ton shele ni cameroun ni won fi arapa yanyana......Ki olorun bawa fopin si oro awon arabi ni

Comments