Awon Dokita ri Aran inu ninu opolo Okunrin kan

Luis Ortiz, omo ile iwe Sacramento State ni California ni won ru digbadigba lor si hospital nigba ti ori fifor bere si ni ara...Igba ti awon dokita shey ayewo ni won ri pe Aran inu wa ninu opolo re, won si sor fun pe ko ni ju Ogban isheju lor lati lor laye.

Comments