Ijamba Oko kan shele ni Porthacourt loni.







Arakunrin to wa jeep yi ni awon eyan sor wipe oun ba trailer kan ja si ona ti o sin sa ere asapajude nigba ti trailer yi kor ti ko fun ni ona ni jeep yi fo kuro ni oju titi ti osi takiti bi eme elo kan..........opolopo awon eniyan lo farapa ti enikan si sor emi re nu.

Comments