Jonathan ati Mama Peace lor ki Dr Eruani




Jonathan ati iyawo re lor ki Dr Eruani fun ti ipapoda baba re tin shey , Chief Allwell Eruani, Aguda the IX, the Obanema ti Emadike ni Bayelsa...Awon ati awon eyan jankanjankan mira ni won jo lor ti won ti ba idile ologbe kedun.

Comments