Tyson Fury fi iya je Wladimir Klitschko








Tyson fury tiko ju omo 27 lor lofi iya to daju je Wladimir klitschko egbe baba re ehehe...Klitshko lotin gba star wipe oun ni world best fun bi igba melo kan bayi sugbon nigba ti owo tyson ba, baba sempe ni o........Sugbon klitschko ki Fury ku ishe ati orire.

Comments