AKU ODUN TITUN O.

Ekabo si odun 2016...Adura mi ni wipe odun yi a tura ko ni le koko mo wa, gbogbo ohun ti a ba dawo le a yori, gbogbo ohun ti a ba bere ni olorun yo se ,a o ni fi oju sokun enikeni ati wipe alafia olorun to tayo imon gbogbo eniyan ni yo je tiwa ninu odun titun yi......Ese pupo fun ife ati ifowosowopo yin........Adenle kolade samuel (kolly moore) lo so be............Ese pupo

Comments