Dele Momodu na ti da Davido loun...........................O so pe Gbomogbomo ni Davido




Leyin gbogbo oro ti Davido so nipa Dele momodu ati Iya omo re, Dele Momodu na ti da loun.O so wipe iwa ika ni Davido ati baba re fe wu nipa jiji omo won gbe lo si ile oke okun............Dele Momodu lotun dupe lowo ijoba Nigeria fun ise takuntakun ti won se ti won o gba ki owo ti awon Adeleke ni fun won ni an fani lati salo oke okun.

Comments