Iyawo Sambo Dasuki lo ke gbajari fun ijoba apapo wipe ki won jo ki won tu oko ohun sile ninu ahamo ti won so si...Leyin igba ti won san 500million ti ijoba apapo so fun idile Sambo Dansuki san ki won le tu le, ni awon DSS tun lo tun mu... Iyawo re lati igba na ni o tin pariwo wipe ki gbogbo eniyan wa gba ohun kale o.
Comments
Post a Comment