Motor Ajagbe kan pa awon olopa meji ni Anambra

Olopa kan ni Anambra lo so emi re nu nigba ti oko ajagbe kan rolu ibudo awon olopa ni oju titi...Oko ajagbe yi ni o break e fail to si gba emi awon olopa meji ni oju ese.

Comments