Saraki so wipe ki se oju emi ohun ni Senator kankan a fi ra motor N47bn.

Saraki loti so wipe gbogbo oro ti awon eyan n so nipa wipe awon senator fe fi N47bn ra  moto yen pe iro nla patapata ni.........wipe ki se oju emi ohun ni iru nkan bayen afi sele.

Comments