Shuaibu Salisu sor wipe oun gbe $47m fun Dansuki ninu brief case mokanla

Director of Finance nigba kan ri Shuaibu Salisu so wipe oun fun ra ohun ti gbe  $47m lo fun Dansuki ri pelu briefcase nigba ti oun si wa ni enu ise lati central bank...Ibi ti awon EFCC tin se iwadi lori oro Dansuki ni oti so oro yi..Oni odawipe PDP ni oko gbogbo owo yi fun.

Comments