Leonardo DiCaprio ti gba ami eye SAG award fun igba akoko




Leyin ti won ti pe ni emarun ototo sugbon ti ko ri ami eye yi gba, Osere kunrin yi ti papa gba ami eye SAG award. Oga ami eye Osere kunrin to mon ere ori itage se ju pelu ere itage  The Revenant. Awon osere ton ba fi igba gba aga ni Eddie Redmayne (The Danish Girl), Michael Fassbender (Steve Jobs), Bryan Cranston (Trumbo), ati Johnny Depp (Black Mass). Leonardo DiCaprio so wipe inu ohun dun pupo lati gba ami eye yi leyin opolopo ise asekara ati adura pelu ijakule lorisirisi ona.

Comments