Olowu ti owu ati awon iyawo re meji lo fun ayeye.

Olowu ti Owu Ile ni Ejigbo local govt area ni ipinle Osun, Oba Muhammad Qozeem Rohji Adekunle Okikiola Ilufemiloye losi ayeye kan pelu awon iyawo meji ti won wo hijab de ile. Omo 38yrs, Oba Qozeem ni okere ju ni ojo ori tosi gba esin ju ninu awon Oba Yoruba.

Comments