Ifeanyi Ubah claims a dollar is now N310............................(Owo dollar ti wa le si N310 Ifanyi Ubah lo sobe)
Politician and businessman, Ifeanyi Ubah, claims in a recent post on facebook that
the exchange rate as of this evening has dropped to N310 to $1.
According to him, the increase in the dollar rate was being manipulated
by some people who will soon be fished out.
Yoruba
Oloselu ati borokini ni, Ifeanyi Ubah so wipe owo dollar ti wa le si N310 si $1.O so ninu atejade to se lori Facebook wipe awon ika ati odaju eyan kan ni ori lede yi lo fa idi ti owo wa fi dibaje, o si se idaniloju wipe gbogbo won ni owo ma ba.

Comments
Post a Comment