Awon olopa ipinle Rivers (Rivers State Police Command) ni ojo aje, mu awon odaran meta kan ti oruko won nje Sodienye Mbatumukeke, 28, Excel Divine Naabe, 25 and Joy Eluwa.
Awon meteta yi ni won ledi apo po lati pa osise ile ise Jumia kan leyin igba ti won gba ero ibanisoro meji lowo re pelu okada kan, won si so oku re si nu salanga.
Oga olopa CP Zaki M. Ahmed, wa gba ni iyanju fun gbogbo omo Nigeria lati ma sora ki won si ma gbiyanju lati ran awon agbofinro lowo pelu iwadi won.
Comments
Post a Comment