Anthony Joshua lu Klitschko lalu bomi nibi idije ise kikan to waye lale ana.

Anthony Joshua ti di elese kikan to ga ju ni agbaye nigba to na ogbeni Klitschko lalu bami lati gba  WBA belt fun ipo IBF.





Comments