Dino Melaye rababa nile lati dupe lowo olorun to ko emi re yo lowo awon agbeni pa to fe gba emi re.





Dino Melaye, lo se atejade yi nibi totin se idupe ni ojo ajinde to sin ra baba niwaju oluwa ni ojo ajinde pelu ebi ati awon ore re. leyin igba ti gbogbo akitiyan awon agbenipa ja si pabo lati gba emi re ni ojo Satide, April 15th, 2017.

Comments