Egbe agbaboolu Man-U se iranti awon ololufe won to so emu won nu ni ilu Calabar.

Awon ololufe Man-U so emi won nu nigba ti ina eletriki jabo lu ibudo ti won ti n wo ere idaraya na ni ose to koja. Ki olorun wa pelu won.

Comments