Gomina Rochas Okorocha ti fi Uriel Oputa se asoju ayeye itagbangba ti ipinle Imo.


Ikan ninu awon oludije ninu idije Big Brother Naija to si je omo bibi ipinle Imo, Uriel Ngozi Oputa ni won ti fi je asoju ayeye itagbangba to ma waye ni ipinle Imo. Gomina ipinle Imo, Rochas Okorocha lo se ikede na lana.

Comments