Oserebirin Mercy Aigbe Gentry lo ke gbajari wipe oko oun Lanre Gentry ti fe fi lulu ba toun je. Oso wipe ojojumo ni o man na oun ti oun si man bo ni asiri, sugbon eleyi koja afarada.
Oko re na se atejade yi lori ero ayelujara instagram wipe oloso ni iyawo oun.
E leyi buru gan ooo 😳
ReplyDelete