Owo te awon odaran meji kan nigba ti won ji Okada ati ero alu-pupu gbe ni ilu Port Harcourt.



Awon Odaran meji kan ni owo awon agbofinro ti te ni adugbo Ogoni Camp, ni Umuebulu ni Port Harcourt, ipinle Rivers ni aro ana. Gege bi iroyin to to wa leti, won ni awon odaran meji yi lo sese jade ni ewon ti won si pada wa ji okada ati ero alupupu gbe.


Comments