Pope Francis lo se abewo si ilu Egypt fun ojo meji lati petu si aawo ton waye laari awon onigbagbo ati awon musulumi, O so wipe ko si bi eyan se le sin olorun ni ododo pelu iwa jagidijagan ati iwa ipaniyan. Olori orilede Ejipiti Abdel
Fattah al-Sisi lo ki kabo ni papa ofurufu Cairo.
Comments
Post a Comment