Arakunrin Bayo Omoboriowo ati Iyawo re ti bi Ibeji.

Ayaworan Aare Mohamodu Buhari , arakunrin Bayo Omoboriowo loni se ikede lori ero ayelujara instagram wipe oun ati iyawo re ti bi omo ibeji lanti lanti. Eku orire.

Comments