Tobi Ohio Igoh, omo ile eko giga Beson Idahosa ati omo ojise Olorun Lawal Igioh ni awon agbebon ti yi ibon pa ni ijoba ipinle Oredo ni ipinle Edo. Isele na sele ni ojo ketadinlogban osu yi, nigba ti omokunrin na pada lo ile re lati ile iwe re. Opolopo awon akeko ni won farapa ninu ikolu awon agbebon na.
Iwadi fi ye wa wipe awon elegbe okunkun lo yin ibon pa omo na nigba ti won lo digunjale.
Comments
Post a Comment