Awon agbenipa kan be ori odomode kunrin kan ni ipinle Rivers.


Oku arakunrin kan ni awon ara adugbo opopona  NTA ni ilu Port Harcourt, ipinle ri loni. Iwadi fi han wipe ori arakunrin na ni awon to se ise ibi na ti ge kuro ni orun re. Eyi waye leyin bi ose kan ti iru ilsele yi waye ni adugbo Rumuosi junction ni eyin ile ijosin Anglican in ipinle River. Awon agbofinro ti bere iwadi to peye lori oro na.

Comments