Awon eyan meji ti ku ninu ile alaja meta (3 storey building) to wo ni ipinle Eko.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Iroyin fi to wa leti wipe awon eyan meji ti ku ninu ile alaja meta to wo ni opopona Daddy Alaja, ni adugbo Oke Arin ni ipinle Eko. Awon osise ajo NEMA se alaye wipe awon eyan merindinlogun ni awon yo ninu awoku ile na.
Comments
Post a Comment