Awon odo ilu Esan ni ipinle Edo ti fi ibinu won han nigba ti iroyin fi to won leti wipe awon Fulani daran-daran fi ipa ba meji ninu awon omobirin ilu na lo ti won si tun fi ake sa won pa. Isele yi je eyi to buru pupo ti o si mu irewesi okan ba awon asoju ati adari ilu na. Awon agbofinro ti wa bere iwadi to peye lori oro na ti won si ti setan lati gbogun ti iwa ipaniyan ati iyanije ti awon Fulani daran-daran n wu kakiri orilede Nigeria.

Comments
Post a Comment