Asoju Aare Yemi Osinbajo, Gomina ipinle eko ati oga agba egbe oloselu APC Asiwaju Bola Tinubu, Oba Eko ,Oba Rilwan Akiolu ati Gomina Ipinle Eko Akinwumi Ambode pelu awon eyan jankan-jankan nidi oselu lo peju sibi ayeye iranti ojoibi ipinle Eko to waye ni ojo abameta ojoketadinlogban osu yi ni Ibudo Gomina ni Ikeja.

Comments
Post a Comment