Ayeye igbeyawo omoba Adedapo Tejuoso. May 31, 2017 Get link Facebook X Pinterest Email Other Apps Omo obabirin Abisoye, omo Oba ilu Osile ti Oke Ona ti ilu Egba, Oba Adedapo Tejuosho, lo se igbeyawo pelu oko afesona re Ogbeni Adebisi Adeoti ni ilu Abeokuta. Opolopo awon eyan jankan-jankan lo peju si bi ayeye igbeyawo na. Comments
Comments
Post a Comment