Gomina ipinle Cross river nigba kan ri, Donald Duke lo ti fi ipinu re lati dije fun ipo aare han.
Ose atejade na nigba ton ba akoroyin fun eto "The Nigerian Symposium for Emerging Leaders", soro. O so wipe oun o ni ife ki ki a ma dide, joko pariwo bi awon omo ile igbimo asofin se ma n se, sugbon oun ni ife si ipo Aare orilrde. O so siwaju si wipe oun ti dije ri, oun o si tun tesiwaju lati dije ti anfani re ba si sile.

Comments
Post a Comment