Egbe agbaboolu Manchester United ti gba ife eye UEFA Europa League.


Iko egbe agbaboolu Manchester United ni ale ojo isegun ti gba ife eye UEFA Europa Leauge nigba ti won na iko egbe agbaboolu Ajax ni omi ayo meji si odo.
  Paul Pogba ati Henrikh Mhikitaryan ni won gba awon omi ayo na wole fun iko egbe agbaboolu Man-u, ti Ajax o si ri ikankan da pada.

Comments