Iyawo Aare, arabirin Aisha Buhari ti lo si ilu UK lati lo duro ti oko re.



Iyawo aare, Aisha Buhari ni aro oni ti lo si ilu London lati lo se abewo si oko re, eni ton gba itoju ni ile iwosan kan ni ilu na. Papa oko ofurufu Nnamdi Azikwe ni iyawo aare na gbe lo.

Comments