Julius Agwu ati iyawo re Ibere se ayeye odun kesan igbeyawo won.



Gbajugbaja alawada Julius Agwu ati iyawo re se ayeye odun kesan ti won gbe ara won ni iyawo. O gbe aworan won si ori ero ayelujara instagram, o si duoe lowo olorun fun ore ofe ati awon omo meji ti o ti fi fun awon.

Atejade to se ni yi ni ede geesi;
"It's ... 9years of marriage and we would still be here. God, you are the redeemer and keeper... please keep us together in Jesus Mighty name, Amen

Comments