Nnamdi Kanu se iranti awon akoni ati ajijagbara fun orilede Biafra to ti ku loju ogun.


Adari awon ajijagbara fun orilede Biafra, ogbeni Nnamdi Kanu loni se iranti awon omoologun ati ajijagbara to ti so emi won nu latari akitiyan won lati gba ominira. Nigba to lo se abewo si ilu Eke Nkpor, o fi ibanuje re han lori awon ajijagbara ti won si so emi wo nu, o si pinu wipe orilede Biafra ko ni pe gba ominira re ki iku awon akoni na ma ba ja si asan.

Comments