Owo awon agbofinro Palm Beach County ba gbajugbaja elere idaraya ni, Ogbeni Tiger Woods nigba to mu oti yo to si n wa oko. Ofin ilu Florida o fi aye gba mimu oti ati wiwa oko, eyi lo fa ti won fi ti Tiger Woods mole ni nkan bi ago meje abo ni aro oni.
Adupe wipe won ti tu sile sugbon won ti gbe oro re lo si ile ejo, fun iwadi ati ijiya to ye fun iru esun na.
Adupe wipe won ti tu sile sugbon won ti gbe oro re lo si ile ejo, fun iwadi ati ijiya to ye fun iru esun na.
Comments
Post a Comment