Awon Fulani Daran-daran pa arakunrin kan ninu oko re ni ipinle Delta. +18


Iroyin fi to wa leti wipe awon Fulani daran-daran kan sa arakunrin kan pa ninu oko re ni ilu Ukomi in Uromi to wa ni ipinle Delta. Awon ara adugbo na ti bere iwode lati ke gbajari fun awon agbofinro.Won se eleyi nitoripe ojo ojumo ni iru isele buruku yi n sele ni ilu won, ti awon agbofinro o si ri nkankan se si.
Oga agba awon olopa to wa ni ipinle na ti wa fi okan won bale wipe lai pe , lai jina owo yo to ba awon Fulani Daran-daran na.

Comments