Gege bi atejade ti arakunrin kan se ni ori ero ayelujara Facebook, alangba jade loju ara arabirin alaboyun kan nigba ton robi ni ile iwosan kan to wa ni ijoba ipinle Obio/Akpor ni ipinle Rivers. Oje iyalenu nla fun gbogbo awon eyan to wa ni be. Awon dokita ile iwosan gan fi iyalenu won han ti won si ke sara si awon aye.
Adura wa ni wipe ki aye ma ye soro gbogbo wa, ki Olorun si fun arabirin na ni alafia re ni pipe. Amin.
Comments
Post a Comment