Nikan bi ose melo kan seyin, Odomode olorin Davido se Utibe ati iya re lanu, nigba to ko ile fun won, tosi san owo ile eko omo na. Ki gbogbo eleyi to sele,Iya omo na tin ba aisan jija kadi, sugbon o se ni lanu wipe aisan na bori arabirin na. Adura wa ni wipe , ki olorun te si afefe ire. Amin.
Comments
Post a Comment