Kini Rochas Okorocha tun gba lowo Femi Fani Kayode bayi?


Femi fani Kayode lo se atejade yi lori ero ayelujara Twitter re lati so oro buruku si Gomina Rochas Okorocha. Eyi waye leyin igba ti Rochas so wipe oro ti Gomina Ayodele Fayose so nipa Aare Muhamoodu Buhari o tona. Femi Fani Kayode pe Rochas Okorocha ni omode ti won de idi fun.

Comments