Ololufe mi dakun mabinu. Lanre Gentry lo so be.


Oko gbajugbaja oserebirin Mercy Aigbe lana se atejade lori ero ayelujara instagram lana lati be iyawo re fun gbogbo esun to fi kan.  O so si waju si wipe ki awon gbagbe gbogbo nkan to ti sele ki awon si tesiwaju.

Comments