Awon omo ologun Nigeria ti mu meji ninu awon omo egbe agbesunmomi Bokoharam. Ogbeni Abubakar Ahmed, ati Aji Maina, ni owo ba ni ojoru ojo kejidinlogbon osu kefa odun 2017 ni Garin Gada ati Kanamma leyin opolopo ofin toto.
Owo ba Abubakar nibi to ti fe gba awon nkan ti won fi sowo si awon omo egbe agbesunmomi na. Aji Maina ni won mu ni Kanamma ni igba ton rin irinajo lati Gamari ati orilede Niger.
Awon agbofinro ti wa bere iwdi to peye lori oro na.
Comments
Post a Comment