Owo ba ole kan nibi to ti fe ji ege (cassava) wa ni ilu Akwa Ibom.


Awon odo agbegbe kan to wa ni ilu Akwa ibomfi arakunrin kan se esin nigba ti owo won ba nibi to tin gbiyanju lati ji ege wa ninu oko oloko. Won ja arakunrin na si ihoho, won si ni ko ma je ege tutu. Leyin gbogbo eleyi ni eni ton se olori agbegbe yi pa lase wipe ki won fi arakunrin na sile ki.
O wa so siwaju wipe ki awon odo ilu na dekun iwa ibaje ati iwa ole ni ilu na.

Comments