Tonto Dikeh, Mercy Aigbe, Dolapo Badmus, Foluke Daramola, fowo sowopo pelu Olori Wuraola lati se iwode fun ilodi si ifiya je ati ilokulo awon obirin ni awujo wa.






Gege bi alase ati oludasile egbe #1in3Africa, Olori Wuraola pelu ati leyin awon osere ti iya ti je lowo oko won bi Foluke Daramola, Tonto Dikeh ati Mercy Aigbe, won se iwode itangbanga lati lodi si ilokulo awon obirin ni awujo wa. Iwode na bere lati agbegbe  Awolowo Road lopopona  Falomo Roundabout. Oga olopa Dolapo Badmus na o gbeyin nibi iwode na.

Comments