Gege bi atejade ti Bobriski eni ti oro re o ye wa boya okunrin ni abi obirin ni, se lori ero ayelujara snapchat, o so wipe 15million ni oun fe fi se ayeye ojo ibi ohun ton bo lona ni ojo kokanlelogbon osu kejo odun 2017.
Hmmmmm kayefi nla gba lele yi o. ehehehe.
Comments
Post a Comment