Aare orilede Ghana nigbakan ri John Mahama ati iyawo re Lordina se ayeye ayajo odun karundinlogbon (25years) igbeyawo won.
Get link
Facebook
X
Pinterest
Email
Other Apps
Aare orilede Ghana nigbakanri John Mahama ati iyawo re Lordina loni se ayeye ayajo odunkarundinlogbon igbeyawo won ni ile itura Gold Coast Hotel to wa ni ilu Accra ni orilede Ghana.
Opolopo awon eyan jankanjankan lo peju sibi ayeye na.
Comments
Post a Comment